Mo lálá ọkùnrin kan tí mo mọ̀ pé ó fún mi ní bàtà dúdú tuntun gẹ́gẹ́ bí ẹ̀bùn Mo kọ lákọ̀ọ́kọ́ ṣùgbọ́n nígbà tó yá, àwọn èèyàn tó yí mi ká bẹ̀rẹ̀ sí gbóríyìn fún nípa bí bàtà náà ṣe rẹwà tó, lẹ́yìn náà ni mo gba bàtà náà, mo sì dúpẹ́ lọ́wọ́ ẹni náà. Emi ko ti gbeyawo